[Mp3] Ebenezer Adeusi - Pentikosi

 



This is a season of power, the season its impact is mostly needed. Ebenezer Adeusi is a gospel singer who has dedicated his life into praising and worshipping God. He also send strong motivational messages to this generation with his angelic voice with strong words of God. 

This song aptly dubbed PENTIKOSI spur the sons of man and daughters of zion of this generation to crave for more and ignite the generation.



Pentikosi Lyrics



Ina Oluwa sokale wa o
Ina Oluwa sokale wa
Ina Oluwa ko sokale wa o

Agbar' Oluwa sokale wa o
Agbar'Oluwa sokale wa
Agbar'Oluwa ko sokale wa o

Bridge: Fire let it fall on me iyeeh iyeeh, let it fall on me

Verse 1: (Ni ojo pentikosi,
 awon omo eyin n sona ariwo ta loke orun daye won gba emi latodo Oluwa)2
Won fede titun soro/2
Iyalenu leyi je awon eniyan ro potin ni 
Won daamu Lai mope 

Chorus: Agbara olorun lode ni ojo pentikosi
Agbara olorun lode Agbara olorun ni

Verse 2: Bi tojo pentikosi
A n wona fun Agbara
Fun wa nibukun ta n fe
Ran emi mimo sokale
Ka le jumo pariwo wipe/2

Chorus: Ina Oluwa sokale wa o
Ina Oluwa sokale wa
Ina Oluwa ko sokale wa o

Agbar' Oluwa sokale wa o
Agbar'Oluwa sokale wa
Agbar'Oluwa ko sokale wa o / repeat both

Mo ti gba Agbara Agbara ai ku
Mo ti gba Agbara Agbara iye /repeat both 6

In case you missed Ebenezer Adeusi previous track, download RARA

Social media Facebook Adeusi Ebenezer

Instagram: ebenezeradeusi

Tweeter: Adeusi_ebenezer

YouTube: ebenezeradeusi 

Comments

Popular posts from this blog

[Mp3] Olayinka Oluwayemisi - Baba E Se (Prod. Kstrum)

[DJ Mix] DJ Pedro OiE - 2024 Trending Songs Mix

[Mp3] Wumi Deslov - Lamba soapy